Dwayne Johnson

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Dwayne Johnson
Remove ads

Dwayne Douglas Johnson (ojoibi May 2, 1972), to tun gbajumo pelu oruko ijaemu re The Rock, je osere, olootu, onisowo, ajaemu totifeyinti ati agbaboolu-elese ti Amerika ara Amerika[1] [2].[1] O je ajaemu fun ile-ise World Wrestling Federation (WWF, loni bi WWE) fun odun mejo ko to di osere. Awon filmu re ti pawo to to US$3.5 billion ni Amerika ati US$10.5 billion lagbaye,[3] to so di ikan ninu awon osere to pawo filmu julo ni gbogbo igba aye.[4]

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads