Eucharia Oluchi Nwaichi

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Eucharia Oluchi Nwaichi jẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ ẹ̀yà Biochemistry, tí ó ní se pẹ̀lú àyíká. Ó tún jẹ́ onímọ̀n Toxicology. Ó gba àmì ẹ̀yẹ tí àwon olóyìnbó n pè ní L'Oreal-UNESCO Awards fún àwon obìnrin ní odún 2013 fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí " ìjìnlẹ̀ ṣàyẹnsí ojutú sí àyík á èérí. Ó sì jẹ́ ikeji ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lati ẹ̀yà íbò lóbìnrin tí ó gba àmì ẹ̀yẹ L'Oreal-UNESCO Awards fún àwon obìnrin nínú ìmọ̀ Síáyẹ́nsì.[1][2]

Remove ads

Ìgbésí ayé

A bí ọ̀mọ̀wé Nwaichi si Ìpínlẹ̀ Ábíá sí idílé Ọ̀gbẹ́ Donatus Nwaichi ti ìlú Ábíá. Ó ní báṣẹ́lọ̀ (B.SC) ati másíta Síáyẹ́nsì (B.Sc) pẹ̀lú dókítọ́réti nínú ìmọ̀ Biochemistry lati Yunifásítì ìlú Port hacourt níbi tí ó tí padà di olùkọ́ ìmọ̀ Biokẹ́mísìrì . kí ó tó darapọ̀ mọ́ Yunifásítì ìlú Port hacourt, Ó ṣiṣẹ́ ilẹ́ "Shell Oil" fún odún kan péré. Iṣẹ́ rẹ̀ tó dáyatọ̀ nínú ìmọ̀ Síáyẹ́nsì ni ó jẹ́ kì ó gba àmì ẹ̀yẹ ti L'Oreal-UNESCO ni odún 2013.[3][4]

Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads