Ezinne Kalu
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ezinne Kalu ni ọkan ninu awọn agbabọọlu inu agbọn obinrin ni Naigiria ti à bini 26, oṣu june ni ọdun 1992 ni Newark, NJ.ojẹ obinrin ti oun gba bọọlu fun Lansmderneau ni ilu France nibi lọwọ lọwọyi[1].
Remove ads
Aṣeyọri
- Kalu ti kopa ninu Olympic to waye ni ilu tokyo ni ósú july ni ọdun 2021, arabinrin naa tun kopa ninu Idije Afrobasket ti o si di champion pẹlu Naigiria D'Tigress nibi tiwọn pe arabinrin na ni gbogbo Irawọ fun tournament[2].
Itọkasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads