Fally Ipupa N'simba (ọjọ́ìbí December 14, 1977), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìtàgé rẹ̀ Fally Ipupa, ní akọrin-akọ̀wéorin, oníjó, ọlọ́rẹ, onígìtá àti olóòtú ará Kóngò. Láti ọdún 1999 dé 2006, ó jẹ́ ìkan nínú ẹgbẹ́ olórin Quartier Latin International, tí Koffi Olomidé dásílẹ̀ ní 1986.[1]
Quick Facts Background information, Orúkọ àbísọ ...
Fally Ipupa |
---|
 Fally Ipupa (2014) |
Background information |
---|
Orúkọ àbísọ | Fally Ipupa N'simba |
---|
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Dicap la merveille, El pibe de oro, El Maravilloso, 3x Hustler, El Rey Mago, Champions love,The king, Eagle Fally Ipupa |
---|
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kejìlá 1977 (1977-12-14) (ọmọ ọdún 47) Kinshasa, Democratic Republic of the Congo |
---|
Irú orin | Ndombolo, soukous, rumba, R&B |
---|
Occupation(s) |
- singer
- dancer
- songwriter
- record producer
- record executive
- philanthropist
|
---|
Instruments | Guitar, Vocal |
---|
Years active | 1989–present |
---|
Labels | F-Victeam, ROCKSTAR4000, Obouo Music, Universal A-Z |
---|
Associated acts |
- Olivia
- Koffi Olomide
- David Monsoh
- Bigg masta G (Muana Mboka)
- Youssou N'Dour
- Salif Keita
- Kasaloo Kyanga
- Icha Kavons
- 2face Idibia
- Youssoupha
- Passi
- Flavour
- Lynnsha
- Lokua Kanza
- DJ Arafat
- Mokobé
- Booba
- R.kelly
- Keri Hilson
- Eve
- Aya Nakamura
|
---|
Close