Federal Polytechnic, Ilaro
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Federal Polytechnic, Ilaro jẹ́ polytechnic kan tó wà ní Ìpínlè Ògùn, ní ìwọ̀ oòrùn gúúsù Nàìjíríà.[1][2]

Àjó Institute of Chartered Accountants of Nigeria ti dá sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí polytechnic kan ṣoṣo ní Nàìjíríà tí ó ti ń mú àdáni tó ga jù lọ ní ẹ̀kọ́ ìṣírò.[3]
Remove ads
Àwọn Ẹ̀ka
Ilé-ẹ̀kọ́ náà ní ẹ̀ka mẹ́fà, èyí ni:[citation needed]
- Ẹ̀ka Management Studies
- Ẹ̀ka Environmental Studies
- Ẹ̀ka Engineering
- Ẹ̀ka Applied Science
- Ẹ̀ka Information Communication and Technology(SCIT)
- Ẹ̀ka Part-Time Studies
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads