Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́

From Wikipedia, the free encyclopedia

Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́
Remove ads

Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́ ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ni óṣu Igbe, ọdún 2023, Ọ̀gbẹ́ni Charles Adélẹ́yẹ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìn dín lọ́gọ́ta ni a fi jẹ ọ̀gá àgbà àti olùdarí tuntun fún ilé ìwé gíga náà ti Ọ̀gbẹ́ni Robert Awóyẹmí tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàleláàdẹ́ta jẹ́ alákòóso yàrá ìkàwé tuntun táa ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn[1].

Quick facts Federal University of Technology, Akure, Motto ...


Ipò ti Yunifasiti Akure wa ni orílẹ̀èdè Naijiria.


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads