Fẹ́mi Adébáyọ̀

Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia

Fẹ́mi Adébáyọ̀
Remove ads

Fẹ́mi Adébáyọ̀ (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1973) [1] jẹ́ amòfin, gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìlọrin ni ìpínlẹ̀ Kwara. Bákan náà Fẹ́mi Adébáyọ̀, títí di ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2019 jẹ́ Olùdámọ̀ràn Pàtàki lórí àṣà, ìrìn-afẹ́ àti iṣẹ́-ọ̀nà fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara àná, Abdulfatai Ahmed. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Adébáyọ̀ Sàlámì, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọ̀gá Bello.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads