Flex Alexander
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Mark Alexander Knox (tí a bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹrin, ọdún 1970), tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Flex Alexander tàbí Flex, jẹ́ òṣèrékùnrin, apanilẹ́rì-ín, àti oníjó láti orílẹ̀-èdè Amerika. Ó bẹ̀ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán ní ọdún 2001 sí ọdún 2006. Alexander tún gbé ẹ̀dá-ìtàn oríṣiríṣi wọ̀ nínú àwọn fíìmù bíi Modern Vampires (1998), The Force (1999), Out Cold (2001), Book of Love: The Definitive Reason Why Men Are Dogs (2002), Gas (2004), Snakes on a Plane (2006), àti Trigger (2020).
Remove ads
Ayé rẹ̀
Alexander, gẹ́gẹ́ bíi àtúnbí fẹ́ olórin R&B kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Shanice Wilson ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejì, ọdún 2000.[1] Wọ́n jọ bí ọmọ méjì, obìnrin kan, Imani Shekinah Alexander-Knox (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ, ọdún 2001) àti ọmọkùnrin Elijah Alexander-Knox (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹta, ọdún 2004). Alexander jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Phi Beta Sigma.[2][3]
Àtòjọ àwọn fíìmù àgbéléwò rẹ̀
Fíìmù
Orí amóhùn-máwòrán
Remove ads
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads