Funsho Adeolu

Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Funsho Adeolu (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án Oṣu Kàrún ún, ọdún 1968) jẹ́ òṣèré sinimá-àgbéléwò, olùdarí àti olóòtú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà [1][2]

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Ìgbé-ayé ni ìgbà èwe

Wọ́n bí Fúnnṣọ́ Adéolú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún ọdún 1968 ni ìpínlẹ̀ Oǹdó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ ní Baptist Academy. Ó kàwé gboyè gíga ni ifásitì ìpínlẹ̀ Oǹdó, Oǹdó State University. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1976. Ère àgbéléwò tó mú un gbajúmọ̀ ni "Countdown to Kusini" àti "Heroes and Zeroes" lọ́dún 1976. Láti ìgbà náà ló ti di ìlúmọ̀ọ́kà lágbo sinimá-àgbéléwò. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa àti èyí tí òun fúnra rẹ̀ tí kọ. Lára wọn ni; Ojú Àpá, Ẹyin Ọká, Jèsù Muṣhin, Àṣírí Owó, Ibojì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Kì í ṣe sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá nìkan ni Fúnṣọ Adéolú ti dáńtọ́, àìmọye sinimá àgbéléwò lédè Gẹ̀ẹ́sì náà lo tí kópa, lára wọn ni; Family Ties, Silenced, Things Fall Apart àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Remove ads

Ìgbé ayé tí ara ẹni

O fẹ arabinrin Mrs. Victoria Adeolu won bí ọmọkunrin meji .[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads