Georg Cantor

From Wikipedia, the free encyclopedia

Georg Cantor
Remove ads

Georg Ferdinand Ludwig Philipp Cantor (pipe /ˈkʰæn-tɔ̝ː(ɚ)/ KANN-tor; German: /ɡ̥eˈɔʁk (ˈfɛʁdinant ˈluːtvɪç ˈfiːlɪp) ˈkʰantɔʁ/ (March 3 [O.S. February 19] 1845[1] – January 6, 1918) je onimo mathimatiiki ara Jemani to gbajumo gege bi oluda ero akojopo, to je ero ipilese ninu mathematiiki. Cantor sedasile pataki idojuko ikookan larin awon akojopo, o setumo awon akojopo alailopin ati awon akojopo agunrege, to si fihan pe awon nomba gidi "po lopolopo" ju awon nomba adaba lo. Looto, agbesiro Cantor so pe "ailopin awon ailopin" wa. O tumo awon nomba onikoko ati eleto ati isiro won. Ise Cantor se pataki nipa oye won, ohun gangan na si mo eyi.[2]

Quick Facts Ìbí, Aláìsí ...



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads