George Akume
Olóṣèlú Nàìjíríà, Gomina ipinle Benue From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
George Akume (bíI Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀ Oṣù kejìlá Ọdún 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue tẹ́lẹ̀. Òhun ni ààrẹ Ile-igbimo Asofin Naijiria tí ó sì jẹ́ aṣojú fún abasoju Àríwá-ìwòorùn Benue láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007. [1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads