Gloria Bámilóyè

Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Gloria Olúṣọlá Bámilóyè tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin oṣù kejì ọdún 1964 jẹ́ gbajúmọ̀ olùdarí, Olóòtú Òṣerébìnri sinimá àgbéléwò, àti ònítíátà ọmọ bíbí ìlú IléṣàÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] She is a co-founder of Mount Zion Drama Ministry.[2]

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Ìgbésí ayé rẹ̀ ni ìbẹ̀rẹ̀

Wọ́n bí Gloria sí ìlú IléṣàÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́dún 1964. Ó kẹ́kọ̀ọ́ láti di olùkọ́ ní Divisional Teachers Training College ní ìlú Ìpetumọ̀dù.[3] Òun àti ọkọ rẹ̀, Mike Bámilóyè ni wọ́n jọ dá ilé iṣẹ́ sini á àgbéléwò Mount Zion Faith Ministry sílẹ̀ lọ́jọ́ karùn-ún oṣù kẹjọ ọdún 1985. Ó ti kópa, tí ó sìn ti darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò àti eré orí ìtàgé lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì. [4] Lọ́dún 2002, ó kọ ìwé kan tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní "The Anxiety of Single Sisters "[5]

Remove ads

Àtòjọ àṣàyàn àwọn sinimá rẹ̀

  • The Haunting Shadows 1 (2005)
  • The Haunting Shadows 2 (2005)
  • The Haunting Shadows 3 ( 2005)
  • High calling 1, 2 & 3 (2020
  • Strategies 1 & 2 (2020)
  • My mother in law 1, 2 & 3 (2020)

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads