Glynn Turman

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Glynn Turman
Remove ads

Glynn Russell Turman tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní, ọdún 1947, jẹ́ òṣèré ilẹ̀ Amẹ́ríkà, ó sì tún jẹ́ ònkọ̀wé, ayẹ̀wéwò olùdarí àti agbátẹrù ètò orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù.

Thumb
Glynn Russell

Ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

Wọ́n bí Turman sí ìlú New York. Ìwádìí fi yé wa pé ó tan mọ́ àwọn ará Edo ní orílẹ̀-èdè Naijiria.[1] Turman kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní High School of Performing Arts tó wà ní agbègbè Manhattan, ní New York, ní ọdún 1965.[2]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

Fíìmù

More information Ọdún, Àkórí ...

Orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù

More information Ọdún, Àkórí ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads