Èdè Gríkì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Èdè Gíríìkì jẹ́ èdè àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Gíríìsì àti Kipru. Álífábẹ́ẹ̀tì wọn jáde láti inú Phoenician script tí ó wá padà di ìkọsílẹ̀ fún èdè Látìn, Cyrillic, Armenian, Coptic, Gothic, àti àwọn ìkọsílẹ̀ mìíràn. Láti nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́ta sẹ́yìn ni wọ́n ti ń sọ èdè Gíríìkì ní Balkan peninsula, [1][2] Ẹ̀rí àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ ni Linear B clay tablet tí wọ́n rí ní Messenia tí ọdún rẹ̀ jẹ́ nǹkan bíi 1450 àti 1350 BC,[3] èyí sì ni ó jẹ́ kí èdè Gíríìkì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè tí ó ní àkọsílẹ̀ tó pẹ́ jùlọ.
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads