Guadalupe Victoria

From Wikipedia, the free encyclopedia

Guadalupe Victoria
Remove ads

Guadalupe Victoria (29 September 1786- 21 March 1843),[1][2] tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ José Miguel Ramón Adaucto Fernández y Félix,[3] jẹ́ ológun ilẹ̀ Mexico nígbà kan rí, tó sì jagun fún Mexico lásìkò ìgbòmìnira wọn. Wọ́n fi jẹ ààrẹ ìlú Mexico àkọ́kọ́.[4]

Quick Facts The Most Excellent, 1st President of Mexico ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads