Halima Abubakar
òṣèré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Halima Abubakar ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹfà ọdún 1985. [2] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [3][4][5]Ní ọdún 2011, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Afro Hollywood Best Actress award.[6][7]
Remove ads
Ìgbé ayé rẹ̀
Wọ́n bí Abubakar ní Ìpínlẹ̀ Kánò , àmọ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Kogí ni.[8] ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bérẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Kano. [9] Ó tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ àkọ́kọ́ ní ú ìmọ̀ Sociology ní ilé-ẹ̀kọ́ Bayero University ní Ìpínlẹ̀ Kano. Abubakar fidí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òun ṣì ní ìbálé ní oṣù kẹwàá ọdún 2018.[10]
Ní inú oṣù Kẹ́rin ọdún 2020, ó kéde pé òun bímọ ọkùnrin[11]
Iṣẹ́ rẹ̀
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré tíátà ní ọdún 2001, níbi tí ó ti kópa nínú eré Rejected. Ó kópa bí olú-èdá ìtàn nínú eré Gangster Paradise. 9un ló dá iṣẹ́ Modehouse Entertainment, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbórin jáde.[12]
Àwọn Fíímù rẹ̀
- Slip of Fate
- Tears of a Child
- Secret Shadows
- Gangster Paradise
- Area Mama
- Men in Love
- Rejected
- Love Castle
- Entrapped
- Dangerous Ivy
- Return of White Hunters
Àwọn ìtọ́kasí
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads