Helen Paul
Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Helen Paul jẹ́ aláwàdà, ólórin àti òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó tún máa ń ṣiṣẹ́ ìpanilẹ́rìn-ín rẹ̀ lórí ètò "stand up Nigeria", Tatafo sì ni a mọ̀ ọ́ sí lórí ìtàgé. Ohun tó yà á sọ́tọ̀ ni óhùn rẹ̀ tí ó dà bí ti ọmọdé bírín tí ó máa ń lò láti fí p
anlẹ́rìn-ínn.[3]
Àìpẹ́ yìí ni ó gbóyè Doctorate nínú Theater Arts láti yunifásítì ilu-ékó
3
Remove ads
Iṣẹ́ rẹ̀
Paul ti ṣiṣẹ́ ìgbétò sáfẹ́fẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìgbétò sáfẹ́fẹ́ bíi Lagos Television (LTV 8),Continental Broadcasting Service (CBS), àti MNet (níbi tí ó ti jùmọ̀ pẹ̀lú àwọn mìíràn gbé ètò JARA sí orí Africa Magic) ní Nàìjíríà.[5]
Ó di gbajúmọ̀ látipasẹ̀ ṣísáwàdà rẹ̀ lórí ètò orí rédíò Wetin dey lórí Rédíò Continental 102.3FM ní ìpínlẹ̀ Èkó. Àwọn èèyàn mọ̀ ọ́ sí "Tatafo" lórí ètò orí rédíò náà.[6]
Remove ads
Iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀
Ní oṣù keje ọdún 2012, ó gbé orin rẹ̀ Welcome Partyjáde. Àwọn orin Afro-Pop bíi "Bojú Bojú", "Vernacular", "Gbedu", "God forbid", orin Afro RnB "Children of the World" àti "Use Calculator(orin ẹ̀kọ́ kan nípa HIV/AIDs)" wà nínú àwo orin náà. Ní ọdún 2018, ó gbé orin audio àti video rẹ̀ "Never Knew" jáde.[7][8]
Àtòjọ àwọn eré tí ó ti ṣe
- 2011 - The Return of Jenifa – role of Tunrayo[9]
- 2012 - A Wish[10] – lead role, a woman who battles cancer
- 2011 - Damage[11] – cameo role
- 2012 - The Place: Chronicle of the Book[12]
- 2014 - Alakada2[13] – supporting role
- 2014 - Akii The Blind[14] – supporting role
- 2012 - Osas (Omoge Benin)[15] – comic act
- 2012 - Igboya[16]
- Mama Put[17] – lead role
Ààtò àwọn àmì ẹ̀yẹ rẹ̀
- 2012 African Film Awards (Afro-Hollywood, UK)[18] – Comedienne of the Year
- 2012 Exquisite Lady of the Year Award (Exquisite Magazine)[19][20] – Female TV Presenter of the Year
- 2014 Exquisite Lady of the Year Award (Nominated)[21] – TV Presenter of the Year (Jara, Africa Magic)
- 2014 Nigerian Broadcasters Merit Awards (NBMA) – Outstanding TV presenter (Female) (Entertainment/Talk Show)[22]
- 2011 City People Entertainment Magazine Award[23] – Female Comedian of the Year
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads