Hillary Rodham Clinton

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Hillary Rodham Clinton
Remove ads

Hillary Diane Rodham Clinton (pípè /ˈhɪləri daɪˈæn ˈrɒdəm ˈklɪntən/; ojoibi October 26, 1947) je oloselu ara orile-ede Amerika. Lowolowo ohun ni Alakoso Oro Okere orile-ede Amerika 67th labe ijoba Aare Barack Obama. O ti je tele bi Alagba Ile Igbimo Asofin Amerika fun Ipinle New York lati 2001 de 2009. Gege bi iyawo Aare Bill Clinton, ohun lo je Iyaafin Akoko Amerika lati 1993 de 2001. Ninu idiboyan 2008, Clinton je eniagbewo fun idaloruko ipo aare egbe oloselu Democratiki.

Quick facts 67th United States Secretary of State, Ààrẹ ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads