Àwọn Ajọọmọnìyàn

From Wikipedia, the free encyclopedia

Àwọn Ajọọmọnìyàn
Remove ads

Ajọ́bọ (Ape) je eyikeyi ninu ébi gbangba Àwọn Aríbíèyàn (Hominoidea) ti awon akodieyan, ninu won na ni awon eniyan wa.

Quick Facts Àwọn Ajọ̀bọ Apes Temporal range: Late Oligocene - Recent, Ìṣètò onísáyẹ́nsì ...

Labe sistemu iyasoto lowo awon ebi meji awon aribieyan lowa:

  • ebi Hylobatidae to ni apa 4 ati iru eya 14 awon gibo, ninu won ni Gibo Lar ati Siamang wa, lapapo won je awon ajobo kekere.
  • ebi awon Ajoeyan (Hominidae) ninu won ni awon osa, awon gorilla, awon eniyan ati awon orangutan[1][2] lapapo a mo won bi awon ajobo ninla.


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads