Akọ́dièyàn

From Wikipedia, the free encyclopedia

Akọ́dièyàn

Akọ́dièyàn (primate) (pípè /ˈpraɪmeɪt/, Àdàkọ:USdict) je ikan ninu ito bioloji Awon Akọ́dièyàn tabi Primates (/praɪˈmeɪtiːz/ prī·mā′·tēz; Latin: "prime, first rank"[2]), ibe na ni prosimians (lamupo mo lemurs, lorises, galagos ati tarsiers ) ati simians (awon obo ati awon aribieyan) wa.[3] Ti a ba yo awon eniyan kuro ti wo wa ni gbogbo orile Aye opo awon akodieyan ungbe ni ibi olooru tabi ibi olooru die ti awon Amerika, Afrika ati Asia.[4]

Quick Facts Ìṣètò onísáyẹ́nsì, Families ...
Akọ́dièyàn
Primates[1]
Temporal range: Late Paleocene–recent
Thumb
Olive Baboon, Papio anubis
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Chordata
Ẹgbẹ́:
Infraclass:
Eutheria
Superorder:
Euarchontoglires
Ìtò:
Àwọn Akọ́dièyàn (Primates)

Linnaeus, 1758
Families
Thumb
Range of the non-human primates (green)
Close


Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.