Ice Cube
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
O'Shea Jackson (ojoibi June 15, 1969), to gbajumo pelu oruko ori itage re Ice Cube, je rapper, osere, olukowe-ere, oludari filmu, ati atokun. O bere ise orin re gegebi ikan ninu awon omo egbe olorin hip-hop C.I.A. ati leyin re o di omo egbe olorin rap N.W.A. Leyin igba to fi N.W.A sile ni December 1989,[2] o bere ise idakorin to yorisirere, ati bi olukowe, oludari, osere ati atokun sinema. Bakanna, o ti se bi ikan ninu awon atokun awon ere ori telifisan Showtime tounje Barbershop ati ti ori telifisan TBS tounje Are We There Yet?, awon mejeeji ti won da lori awon filmu to se bi osere.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads