Ilaje
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìlàje jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Òndó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú náà wà ní Igbokoda. Ẹ̀yà Yorùbá yìí dá yàtọ̀, nínú èdè ẹnu wọn, àkójọpọ̀ ìlú bí i Ondo, Ogun àti Delta ló bí ìlú yìí.
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
