Ìpínlẹ̀ Jigawa
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìpínlẹ̀ Jigawa jẹ́ ọkan nínu ìpínlè mẹ́rìndínlógójì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yí wà ní apá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1991 láti apá ìwọ̀ Oòrùn gúsù Kánò, Jigawa wa ni ààlà tó wà lárin orílẹ̀-èdè Niger ati orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Dutse ni olú ìlú fún Ìpínlẹ̀ náà, tí ósìjẹ́ ìlú tí o tóbi julọ ní Ìpínlẹ̀ Jigawa.
Remove ads
Awọn èdè
Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Jigawa ní Bade, Warji, Duwai. Hausa ati Fula je èdè ti wọn n sọ jù ni ìpínlè Jigawa.[3]
Ijọba Ìbílẹ̀
Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Jigawa jẹ́ mẹ́tàdìnlógbọ̀n. Awọn ná ní:
- Auyo
- Babura
- Biriniwa
- Birnin Kudu
- Buji
- Dutse
- Gagarawa
- Garki
- Gumel
- Guri
- Gwaram
- Gwiwa
- Hadejia
- Jahun
- Kafin Hausa
- Kaugama
- Kazaure
- Kiri Kasama
- Kiyawa
- Maigatari
- Malam Madori
- Miga
- Ringim
- Roni
- Sule Tankarkar
- Taura
- Yankwashi
Ilé ẹ̀kọ́ gíga
- Federal University Dutse, Jigawa State
- Sule Lamido University, Kafin Hausa, Jigawa State
- Khadija University Majia, Jigawa State
- Jigawa State Institute of Information Technology, Kazaure
- Binyaminu Usman College of Agriculture, Hadejia, Jigawa State.
- Government Science Technical College, Binin Kudu
- Jigawa State Polytechnic Dutse
- Government Science Technical College, Ringim
- Government Technical College, Hadejia
- Kazaure Innovation Institute, Jigawa State
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads