Dutse
Olú-ìlú ìpínlè Jigawa, Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Dutse ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Jigawa ní Ariwa Nàìjíríà. Ibẹ̀ ni Yunifásitì ìlú Dutse tí wón dá kalẹ̀ ní oṣù kọkànlá ọdún 2011kalẹ̀ sí. Àwọn olùgbé Dutse jẹ́ 153,000,[1] òun sì ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ Jigawa.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Àwọn Ìtókasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads

