Irin

From Wikipedia, the free encyclopedia

Irin
Remove ads

Irin je àdàlú ni pataki julo idẹ pelu akoonu adú larin 0.2 and 1.7 or 2.04% ni iwuwosi. Adu ni o dinwoju lati se adalu mo idẹ sugbon a tun le lo adalu awon apilese miran manganisi, kromiomu, banadiomu ati wolframu.[1] Adu ati awon apilese miran n sise bi imule sinsin lati dena ifo ninu atomu ayonu.

Thumb
Afárá irin
Thumb
Okùn irin




References

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads