Jacob Bernoulli

From Wikipedia, the free encyclopedia

Jacob Bernoulli
Remove ads


Jacob Bernoulli tí a mọ̀ bákan náà sí James tàbí Jacques (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1654, tí ó sìn di olóògbé ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1705) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Switzerland àti ọ̀kan lára àwọn onímọ̀ Ìṣirò pàtàkì tó pọ̀ nínú ẹbí Bernoulli.[1][2]

Quick facts Ìbí, Aláìsí ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads