Joseph Stalin

From Wikipedia, the free encyclopedia

Joseph Stalin
Remove ads

Joseph Stalin (orúko àbísọ Ioseb Besarionis dze Jughashvili ní èdè Georgia tàbí Iosif Vissarionovich Dzhugashvili ní orúko bàbá ní Russia; 18 December 1878 – 5 March 1953) lo jẹ́ Akòwé Àgbà Ẹgbẹ́ Kọ́mmústí tí Ìsòkan Sofieti fún Ìgbìmò Gbàngbà láti 1922 títí de ọjọ́ ikú re ní 1953.[1] Léyìn ikú Lenin ní 1924, o di olórí orílẹ̀-èdè Ìsòkan Sofieti.[2]

Quick Facts Generalissimo, 1st General Secretary of the Communist Party of the Soviet Union ...
Remove ads

Ìtókasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads