Kamala Harris

From Wikipedia, the free encyclopedia

Kamala Harris
Remove ads

Kamala Devi Harris ( /ˈkɑːmələ/ KAH--lə;[1][2] ọjọ́ìbí October 20, 1964)[3] ni olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ará Amẹ́ríkà tó wà ní ipò gẹ́gẹ́bí alàgbà ilẹ́ aṣòfin Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti Kalifọ́níà láti ọdún 2017. Òhun ni wọ́n pè lórúkọ fún ipò ìgbákejì ààrẹJoe Biden fún Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì nínú ìdìbòyan ààrẹ ọdún 2020Amẹ́ríkà.

Quick Facts United States Senator from California, Asíwájú ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads