Kashim Shettima

Igbakeji Aare orile-ede Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Kashim Shettima
Remove ads

Kashim Shettima (ọjọ́ ìbí; ọjọ́ kejì oṣù kẹsàn-án ọdún 1966) jẹ́ olóṣèlú tí ó jẹ́ igbá-kejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ lọ́wọ́,[1] òun ni ó jẹ́ Senato agbègbè Bornu Central láàrin ọdún 2019 sí 2023, ó sì tún jẹ́ Gómìnà Ipinle Borno láàrin ọdún 2011 sí 2019.

Quick Facts Gomina Ipinle Borno, Asíwájú ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads