Kcee

From Wikipedia, the free encyclopedia

Kcee
Remove ads

Kingsley Chinweike Okonkwo , tí a mọ̀ sí Kcee, jẹ́ olórin Nàìjíríà àti ẹni tí ó máa ń kọ orin. Ó ti fìgbà kan wà nínú ẹgbẹ́ orin Hip Hop tí wọ́n ń pè ní Kc Presh. Ó wá láti ìlú ní Uli ní ìjọba ìbílẹ̀ Ihiala ní Ìpínlẹ̀ Anambra, Nàìjíríà. Ní báyìí, ó ní àdéhùn iṣẹ́ pẹ̀lú Five Star Music. Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Del B, olùgbéjáde rẹ́kọ́ọ̀dù tí ó gbajúgbajà fún gbígbé orin "Limpopo" jáde. Òun ni ẹ̀gbọ́n E-money.

Quick Facts Background information, Orúkọ àbísọ ...
Remove ads

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé àti iṣẹ́ orin

Kcee àti ìkejì rẹ̀ tí wọ́n jọ ń kọrin, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ hajie jọ ń kọrin papọ̀ fún ọdún méjìlá. Wọ́n pàdé nínú Ẹgbẹ́ akọrin ìjọ , wọ́n jọ wà nínú ẹgbẹ́ akọrin papọ̀ títí tí wọ́n fi lọ fún ìdíje ètò ojú-ayé Star Quest lórí TV, tí àwọn méjèèjì sì gbégbá oróókè lórí ètò náà. Àwọn iṣẹ́ wọn papọ̀ gẹ́gẹ́ bí i ẹgbẹ́ olórin fún wọn ní òkìkí díẹ̀ di ọdún 2011 tí wọ́n pínyà, tí oníkálukú sì bẹ̀rẹ̀ sí í lé iṣẹ́ orin rẹ̀ lọ́tọ́ọ̀tọ̀. Kcee kọ "Sweet Mary J" [1] tí ó jẹ́ orin àdákọ rẹ àkọ́kọ́ ní ọdún 2020.

Remove ads

Àwọn orin rẹ̀

Àwọn àwo

  • Takeover (2013)
  • Attention To Detail (2017)

Àwọn fídíò rẹ̀

More information ọdún, àkọlé ...

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ àti yíyàn fún gbígba àmì-ẹ̀yẹ

More information Year, Awards ceremony ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads