Kenneth Okonkwo
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Kenneth Okonkwo (ti a bi ni oṣù Kọkànlá ní ọjọ́ Kẹfà, ọdún 1968) ó jẹ́ Òṣeré Nàìjíríà kan, agbẹjọ́rò àti olóṣèlú, tí a mọ ipá rẹ nínú fíìmù Living in Bondage bí Andy Okeke.
Remove ads
Iṣẹ́ rẹ
Ní ọdún 2013 o gba Àmì Eye Africa Movie Academy Award lórí idànìmọ̀ Pàtàkì tí Pillars Nollywood. [1] Ọdún 2015 ní wọn fún ní àmì-ẹyẹ pàtàkì láti ọdọ àwọn adarí the City People Entertainment Awards fún ipá rẹ si ìdàgbàsókè eré ìdárayá ní Nàìjíríà. [2] [3] [4] [5] [6] [7] [8] [9] [10]
Filmography
Remove ads
Wo eléyìí na
- 9th Africa Movie Academy Awards
Awọn itọkasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads