Kerry Washington
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Kerry Marisa Washington[1] (ọjọ́-ìbí January 31, 1977)[2][3][4] jẹ́ olóòtú, olùdarí àti Òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó di gbajúmọ́ látàrí ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Olivia Pope nínú eré orí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Scandal (2012–2018).[5]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads