Khalifa bin Zayed Al Nahyan

From Wikipedia, the free encyclopedia

Khalifa bin Zayed Al Nahyan
Remove ads

Khalifa bin Zayed bin Sultan Al Nahyan to je Sheikh (Lárúbáwá: خليفة بن زايد بن سلطان آل نهيان), (ojoibi 1948), ti won unpe ni Sheikh Khalifa ni Aare orile-ede awon Emirati Arabu Ajepiparapo (UAE) ati emiri ilu Abu Dhabi lowolowo. O bo si ipo mejeji na ni 3 November 2004, nigba to dipo baba re Zayed bin Sultan Al Nahyan, to ku ni ojo kan seyin ojo na.

Quick Facts 2nd President of the United Arab Emirates, Alákóso Àgbà ...
Remove ads


Remove ads

Itokasi

Loading content...
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads