Látfíà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Látfíà
Remove ads

Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv) je orile-ede ni agbegbe Baltiki ni Apaariwa Europe. O ni bode ni ariwa mo Estonia (343 km), ni guusu mo Lithuania (588 km), ni ilaorun mo Rosia (276 km), ati ni guusuilaorun mo Belarus (141 km).[4] Niwaju Omi-okun Baltiki ni iwoorun ni Swidin wa. Agbegbe Látfíà borile to to 64,589 km2 (24,938 sq mi) o si ni ojuoju tutu kakiri odun.

Quick Facts Republic of Latvia Latvijas Republika, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads