Lafia

From Wikipedia, the free encyclopedia

Lafia
Remove ads

Lafia jẹ́ ìlú kan ní àárín gbùngbùn Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Nasarawa ó sì ní àwọn olùgbé tí ó tó 330,712 ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà sọ.[1] Òun ni ìlú tí ó tóbi jù ní ìpínlẹ̀ Nasarawa.

Quick facts Lafia Lafiyan, Country ...
Remove ads

Ìtàn

Àwọn míràn mo ìlú Lafia sí Lafian bare-Bari. Muhammadu Dunama ni ó dá ìlú náà kalẹ̀ ní ọdún 17k.

Àwọn Ìtókasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads