Marion Walter Jacobs (May 1, 1930 – February 15, 1968), tó gbajúmọ̀ bí i Little Walter, jẹ́ olórin, akọrin, àti akọ̀wé-orin blues. Ó jẹ́ ará ilẹl America tí ó kọrin lọ́nà tuntun bí i Jimi Hendrix.[1] Ìṣọwọ́korin rẹ̀ mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ìrètí ohun tí orin blues máa dà lọ́jọ́ iwájú.[2]