Manuel Dorrego
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Manuel Dorrego (11 June 1787 – 13 December 1828) je ara orile-ede Argentina ati ọmọ-ólógun. Ó jẹ́ Gómìnà Buenos Aires ní ọdún 1820, tí wón sì yan sipo lekansi laarin ọdún 1827 si 1828.
Remove ads
Ìgbésíayé àti òṣèlú
Dorrego ni wón bí si Buenos Aires ni ọjọ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1787 sí ìdílé José Antonio do Rego, ati María de la Ascensión Salas. Ó bẹ̀rẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ Real Colegio de San Carlos ní ọdún 1803, ti o si kuro lọ síReal Universidad de San Felipe ni Captaincy General of Chile lati keko rẹ lọ.[1]
O kó kúrò lọ sí United Provinces of the Río de la Plata (tí wón pe ni Argentina lóde òní), ti o si dárapọ̀ mọn Army of the North, lábẹ asẹ Manuel Belgrano. Ó jà níbi awọn ogun Tucumán ati Salta, tí ò sìse loju ogun mejeji.[1]
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads