Maya Angelou
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Maya Angelou ( /ˈmaɪ.ə ˈændʒəloʊ/; tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Marguerite Annie Johnson; April 4, 1928 – May 28, 2014) jẹ́ olùkọ̀wé àti eléwì àpilẹ̀kọ ará ilẹ̀ Amẹ́ríkà.[1] O di gbajúmọ̀ lórí àwọn ìwé tí ó kọ nípa ìgbésí-ayé ara-ẹni rẹ̀ mẹ́fà tó kọ tí wọ́n sì dá lórí ìgbà èwe àti ìgbà ọdọ́ rẹ̀. Àkọ́kọ́ nínú àwọn ìwé náà ni: I Know Why the Caged Bird Sings[2]tí ó kọ ní ọdún (1969), èyí dà lórí ìgbà èwe rẹ̀ títí dé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún. Ìwé rẹ̀ yí jẹ́ kó di gbajúmọ̀ káàkiri ayé, wọ́n yàn án fún àmì ẹ̀yẹ Ẹ̀bùn Ìwé Orílè-ẹ̀dẹ̀ Améríkà. O tí gbà ìwé ẹ̀rí àmì ẹ̀ye bí ọgbọ̀n, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n dá orúkọ rẹ̀ fún ẹ̀bùn Ẹ̀bùn Pulitzer fún ìwé ewì 1971 re, Just Give Me a Cool Drink of Water 'Fore I Diiie.[3]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Ìtókasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads