Mẹ́ṣíkò

From Wikipedia, the free encyclopedia

Mẹ́ṣíkò
Remove ads

Mexico jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Apá Àríwá Amẹ́ríkà. Èdè Sípéènì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀. Apá gúúsù orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ló wà. Àwọn ọmọ Sípéènì ṣẹ́gun Mẹ́ṣíkò l'ọ́dún 1519. Ọ̀pọ̀ àwọn Mestizo wà nínú àwọn ènìyàn tó wà ní Mẹ́síkò, ìyẹn ni àwọn tí òbí wọn jẹ́ apá kan Òyìnbó àti apá kan ọmọ ìbílẹ̀ Mẹ́ṣíkò. L'ọ́dún 1821 orílẹ̀-èdè yìí gbà òmìnira lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà àti ogun. Wọ́n di Orílẹ̀-Èdè Olómìnira l'ọ́dún 1824. Wọn jẹ aṣiwere nitori wọn ro pe ohun gbogbo ko yẹ tabi ibinu.

Quick Facts Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́ṣíkò Aṣọ̀kanUnited Mexican States Mexihco Tlacetililli Tlahtohcayotl;, Àwọn èdè ìṣẹ́ọba ...

There is no official language stipulated in the constitution. However, the General Law of Linguistic Rights for the Indigenous Peoples recognizes all Amerindian minority languages, along with Spanish, as national languages and equally valid in territories where spoken. The government recognizes 62 indigenous languages, and more variants which are mutually unintelligible.Comision Nacional para el Desarrollo de los Pueblos Indigenas. CDI. México Archived 2011-05-01 at the Wayback Machine. [5]

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads