Michael Rubens Bloomberg[2] tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1942 (February 14, 1942) jẹ́ pàràkòyí olóṣèlú, oníṣòwò àti oǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Òun ni Aláṣẹ àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ Bloomberg L.P., Bloomberg ni Alákòóso Ìlú-ńlá New York láti ọdún 2002 sí 2013. Lọ́wọ́ báyìí, òun ní adíje dùpò Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Democratic Party tí yóò wáyé lọ́dún 2020.[3]
Quick facts 108th Alákòóso Ìlú-ńlá New York, Deputy ...
Michael Bloomberg |
---|
 |
|
108th Alákòóso Ìlú-ńlá New York |
---|
In office January 1, 2002 – December 31, 2013 |
Deputy | Patricia Harris |
---|
Asíwájú | Rudy Giuliani |
---|
Arọ́pò | Bill de Blasio |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | Michael Rubens Bloomberg 14 Oṣù Kejì 1942 (1942-02-14) (ọmọ ọdún 83) Boston, Massachusetts, U.S. |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic (kí ó tó di 2001, 2018–títí di àkókò yìí) |
---|
Other political affiliations | Independent (2007–2018) Republican (2001–2007) |
---|
(Àwọn) olólùfẹ́ | Susan Brown-Meyer (m. 1975 ; div. 1993 ) |
---|
Domestic partner | Diana Taylor (2000–àkókò yìí |
---|
Àwọn ọmọ | 2, including Georgina |
---|
Education | Johns Hopkins University (BS) Harvard University (MBA) |
---|
Net worth | US$61.8 billion (February 2020)[1] |
---|
Signature |  |
---|
Website | Official website |
---|
Close