Michael Clarke Duncan
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Michael Clarke Duncan (December 10, 1957 – September 3, 2012) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ókó nínú eré The Green Mile (1999) tí wọ́n sì fa orúkọ rẹ̀ sílẹ fún àmì ẹ̀yẹ Akádẹ́mì.[1]. Ní ọdún 2009, ó jọ̀wọ́ ẹran jíjẹ tí ó sì jádé fún ìpolongo PETA, tí ó ń jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ̀ ìlera tí ó rọ̀ mọ́ ewé jíjẹ.[2][3]
![]() |
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Michael Clarke Duncan |

Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads