Michael D. Higgins

From Wikipedia, the free encyclopedia

Michael D. Higgins
Remove ads

Michael Daniel Higgins (Irish: Mícheál D. Ó hUiginn; bibi 18 April 1941) ni aare adiboyan ile Irelandi, yio si di Aare ile Irelandi kesan, leyin igb to bori[3] idiboyan aare Irelandi 2011 to waye ni 27 October 2011. Higgins je oloselu, akoewi, aseoroalawujo,[4] akowe ati akede ara Irelandi. Higgins je Aare Labour Party of Ireland titi di igba to feyinti kuro nibi egbe oloselu leyin idiboyan aare.[1] Teletele o je Teachta Dála (TD) fun agbegbe Galway West,[5] be sini ohun lo je Alakoso fun Iseona, Asa ati Gaeltacht lati 1993 de 1997.

Quick facts President-elect of Ireland, Succeeding ...



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads