Mode 9

From Wikipedia, the free encyclopedia

Mode 9
Remove ads

Babatunde Olusegun Adewale[1][2](tí wọ́n bí ní June 14, 1975), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Modenine, jẹ́ olórin.[3][4] Ní ọdún 2014, ó ṣàgbéjáde orin kan, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Super Human" pẹ̀lú akọrin ti orílẹ̀-èdè Jamaica kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Canibus.[5][6]

Quick Facts Modenine, Background information ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads