Mojave Desert

From Wikipedia, the free encyclopedia

Mojave Desertmap
Remove ads

Asale Mojave California ni asale yii wa ni iwo-oorun Amerika. Awon nnkan ti o wa ni asale yii ni yanrin, okuta, volcanic rock ati awon adagun odo (lake) ti o ti gbe. O fe to 15,000 square mile.. Loooto, won ko le dako ni Mojave desert, won maa n ri awon ohun alumo-onni ile bii goolu, silifa ati tungsten ni ibe.

Quick facts Orílẹ̀-èdè, States ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads