Monalisa Chinda

òṣèré orí ìtàgé, o nṣe fíìmù àti gbajúmọ̀ orí ẹ̀rọ amóhùmáwòrán From Wikipedia, the free encyclopedia

Monalisa Chinda
Remove ads

Monalisa Chinda tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 (13th September 1974)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ olóòtú ètò orí tẹlifíṣàn àti gbajúmọ̀ olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́.[2]

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads