Mpumalanga

From Wikipedia, the free encyclopedia

Mpumalanga
Remove ads

Mpumalanga jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn igberiko 9 ní orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfíríkà. Mpumalanga jẹ́ ọ̀kan gbòógì ìlú tí ó ni ibi ìgbafẹ́ púpọ̀. Àwọn ilé ìgbafẹ́ tí wọ́n wà níbẹ̀: Odo Blyde Kanyo, Ipase ibere, Fèrèsé Ọlọ́run, Age gagara ti o wa ni kilomita marun-din-logoji Graskopu ni oju ona Panorama, Ogba Lofedi ti oni orisirisi nkan ogbin ti o le ni ẹgbẹ̀rún méjì, Iho gbohun gbohun, Adágún odò kiirisi irú rẹ̀ tí ó tóbi ju ní gúúsù Áfíríkà, Oke ikoja, Ilé ìgbafẹ́ Gustafu.

Quick facts Country, Established ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads