Mársì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Mársì
Remove ads

Mársì jẹ́ ìsọ̀gbé Oòrùn kẹrin lati Oòrùn tí ó sì jẹ́ ìkejì ìsọgbé tí ó kéré jù lẹ́yìn Mercury nínú ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po. Wón sọọ́ lórúkọ Roman god of war, wọ́n ma ń sábà pèé ní "ìsọ̀gbé Oòrùn Pupa".[1][2] nítori àyè tí iron oxide gbà lóju rẹ̀ jẹ́ kó ní ìrísí pupa.

Quick Facts Ìfúnlọ́rúkọ, Ìpolongo ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads