Nina Simone
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Nina Simone (/ˈniːnə sɨˈmoʊn/; oruko abiso Eunice Kathleen Waymon; February 21, 1933 – April 21, 2003) je omo ile Amerika akorin, oluko orin, atepiano, atorin, ati alakitiyan awon eto araalu to ko orin jazz. Simone fe di atepiano orin klasik bo se n sise lopo iru orin ti ninu won je klasik, jazz, blues, soul, folk, R&B, gospel, ati pop.
Botilejepe won woarun aisan isiyemeji,[1] aisan iyiwapada lainidi ati skitsofrenia,[2] Simone gbe awon orin to ju 40 jade, opo won larin 1958 — nigba to se debut pelu Little Girl Blue — ati 1974.
Remove ads
Igbesiaye ati ise
Igba ewe (1933–1954)
Simone was born Eunice Kathleen Waymon in Tryon, North Carolina. One of eight children in a poor family, she began playing piano at age three; the first song she learned was "God Be With You, Till We Meet Again". Demonstrating a talent with the instrument, she performed at her local church, but her concert debut, a classical recital, was given when she was twelve. Simone later claimed that during this performance her parents, who had taken seats in the front row, were forced to move to the back of the hall to make way for white people. Simone said she refused to play until her parents were moved back to the front,[3][4] the incident contributing to her later involvement in the civil rights movement.
Remove ads
Atojo awon awo orin
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
