Nollywood

From Wikipedia, the free encyclopedia

Nollywood
Remove ads

Àdàkọ:Use Nigerian English Àdàkọ:Àṣà ilẹ̀ Nàìjíríà Nollywood, Èyí jẹ́ àkàǹpọ̀ orúkọ Nigeria àti Sinimá orílẹ̀-èdè America ti wọ́n mọ̀ sí Hollywood, tí orúkọ rẹ̀ sí ń kọ́kọ́ jẹ́ Sinimá tí orílè èdè Nàìjíríà tàbí ilé iṣé fíìmù Nàìjíríà.[1] Ìpilẹ̀ṣẹ̀ tí a lè ṣe ìtọpinpin fún ọ̀rọ̀ náà ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ọdún 2000, tí o tọpa rẹ̀ sí àkọọlẹ kàn ní inú ìwé ìròyìn The New York Times.[2][3] Látàrí ìtàn, ìdàgbàsókè àti bí ayé tí ń yìí, kò ì tí sí ìtumò kan ní pàtó tí wọ́n faramọ̀ fún orúkọ náà láti máa lò, èyí sí jẹ́ òun àríyànjiyàn.[4][5]

Thumb
Àwòrán àwọn oniṣẹ́ sinema tó ń ya fíìmù
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa orúkọ yìí tí ṣe Nollywood. Fún fún àlàyé kíkún lórí Ilé Iṣẹ́ Fíìmù tí Nàìjíríà, ẹ wo: Cinema ti Nàìjíríà.
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads