Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè ìṣọ̀kan Amẹ́ríkà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ohioi/ɵˈhaɪ.oʊ/ jé ìpinlè aarin-oorun ní orílè-èdè isokan tí Amerika [15] Ìpínlè Ohio ní ìpinlè kẹrinlelọgbọn tí oní agbegbe jù ní orílè-èdè Isokan Amerika, [16]
Ohun sì ní ìpinlè keje tí óní olùgbé jù ní Orílè-èdè isokan America pèlú olùgbé 11.5 million. [17]
Oluilu ipinle Ohio ni Columbus.
Quick facts
State of Ohio
Flag
Èdìdí
Ìlàjẹ́: The Buckeye State; The Mother of Presidents; Birthplace of Aviation; The Heart of It All